9ice - Iya Alariya lyrics

[9ice - Iya Alariya lyrics]

Emi ni kan kan mow a moni baba ni gbejo
Mo wowo ra mo gbagbe iyin ola ati egan
Iya laari ya ken ken eh
Iya laari ya ken ken eh eh
Iya laari ya ken ken ma jo mayo
Iya laari ya ken ken eh eh
Ti mob a lo pelu imo kan
Taabi mo re koja lo pelu inu kan
Sa dede ni blessing awa si
Odo mi toori mo gbagbo
Egbegberun subun lotun loosi me
Nkan kan koni se omo olorun
Okeere opoju temi emi nikankan mow a
Moni baba ni igbejo emi ni kan kan mow a
Moni baba ni gbejo
Mo wowo ra mo gbagbe iyin ola ati egan
Iya laari ya ken ken eh
Iya laari ya ken ken eh eh
Iya laari ya ken ken ma jo mayo
Iya laari ya ken kеn eh eh
Ise owo mi koni di ibajе
Won tie muruwu muruw mo mi wan ko fe te o
Bab ti se ileri pe ma jaiye mi pe pe pe pe
Atele ese n te ono
Ajoke aiye, asake orun koni si mi lono
Eye se inu binu si mi ma
Mo ni baba ni igbejo emi ni kan kan mowa
Moni baba ni gbejo
Mo wowo ra mo gbagbe iyin ola ati egan
Iya laari ya ken ken eh
Iya laari ya ken ken eh eh
Iya laari ya ken ken ma jo mayo
Iya laari ya ken ken eh eh

Interpretation for


Add Interpretation

Add extended interpretation

If you know what the artist is talking about, can read between the lines, and know the history of the song, you can add interpretation to the lyrics. After checking by our editors, we will add it as the official interpretation of the song!

Latest added interpretations to lyrics

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z #
Interpret