Asa - Happy People lyrics

[Asa - Happy People lyrics]

O òré mi Láídé níbo ló dà l'ójó Saturday yìí
Hmmm wón se party níhìn o
L'Ókè súnáà léhìn kùlé àwon Làtí

Ànkárá la dá kòstúmù la wò
Kosé l'afi gbóyàn sókè bàtà mí ti ready

Ànkárá la dá kòstúmù la wò
Kosé l'afi gbóyàn sókè bàtà mí ti ready
Oh we're happy people and that's who we are
We're having fun
We're the children of the sun

Oh we're happy people and that's who we are
We don't care we're the children of the sun

O òré mi Laide níbo ló kàn l'ójó Sunday yìí
Hmmm wón gbéyàwó níhin o
L'Ókè pópó légbe ilé àwon Toyeeb

Ànkárá la dá kòstúmù la wò


Kosé l'afi gbóyàn sókè bàtà mí ti ready

Ànkárá la dá gèlè búlúù la wò
Kosé l'afi gbóyàn sókè bàtà mí ti ready

Oh we're happy people and that's who we are
We're having fun
We are the children of the sun

Oh oh we happy people and that's who we are
We don't care we are the children of the sun

Oh oh we happy people and that's who we are
We're having fun
We are the children of the sun

Oh oh we happy people and that's who we are
Oh we don't care
We are the children of the sun

Oh oh we happy people
And that's who we are now oh we don't care
We are the children of the sun

Interpretation for


Add Interpretation

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z #
Interpret