Asa - Iba lyrics
[Asa - Iba lyrics]
Bacause of you i dey live, I dey breath
I dey eat
So, I wanna have some talk with you
Nitori re mose n lola nitori re mose n s'oge
Nitori re mose n ra moto
Mowole, M'oboluwa mi soro
Nitori re mose wa laye
Nitori re mose n woso sara
Nitori re moji l'owuro mow'aye mi lode ye
A o, Aa a o o ibafeledu'a a o, Aa a o o
Mowole, M'obolowa mi soro
Nitori re mose n gbo iroyin ayo
Lais'owo laisi nkankan iya oni, layoola o
B'oluwa tiwi, be naa lori
Jiji moji lowuro moji si inu ipese re
Ayo at'alafia ye ye
O, o o oni pe ki n ma se beru
A o, Aa a o o ibafeledu'a a o, Aa a o o
Mowole, M'obolowa mi soro
Melo la fe so melo lo si n bowa
Melo la fe so, eh melo lo si n bowa
Nitori re mose n sa ko, everyday, eh eh
Nitori re mojijo lese mi, oh oh oh, oh oh
Ninu iponju, Ninu idamu b'ebi ba n p'ona
Mawole, maboluwa mi soro
B'emi o le yan baye ba foju dimi
B'emi o le ni mawole, maboluwa mi soro
A o, Aa a o o ibafeledu'a a o, Aa a o o
Mowole, M'obolowa mi soro
Ninu iponju, Ninu idamu b'ebi ba n p'ona
Mawole, maboluwa mi soro
Mioni foju sunkun mo o
Aye loja, oh oh orun orunile
And that's fine by me eh eh
Oh ye ye bring it down oh oh