Asake - 2:30 lyrics

Ahmed Ololade [Nigeria]

[Asake - 2:30 lyrics]

Uh obah
What demma say? Obah
Run hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm

Awa de, awa de de
Awa lọmọ to n sọ ti o seke, ye
Orimọlade gbemi debẹ jigan jigan
Ẹsẹ mi o delẹ, delẹ alaye mi stop shebẹ
O fẹ jenbi, otun fẹ jenbẹ opọ se
Agbawo, fẹnu fo fence sun sẹ yin
Amọrawa, sho get? Abinibi yato s'ability
Ẹsọ fun wọn tan ba teri si wọn ma pa lori
Tẹnu kọ, emi promising
Awọn tẹ fọ fun, fọ fun mi tori ko sẹ lomi
Many many fẹ dabi mi eri bi
Ẹgbọlorun tobi mo da aso-ẹbi for my country
You can call me Mr Money

Hmm, hmm, hmm, hmm hmm, hmm, hmm, hmm
2: 30 fẹlu oya ka turn up
Kilẹ to mọ hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm ye, ye, ye
2: 30 fẹlu (Thirty fẹlu) oya ka turn up
Kilẹ to mọ

Ere moba wa kosi ja shokoto pen pe, ye
Ayenika, yebo, yeba formation logba, ye ja
Ọmọ'yami ko stay wise
Tranquility, tranquility
I no get time to dey form activity
Kole kalas, I dey find stability
Like abacha, monеy long infinity
What's the chances? What's the probability?
To see a bеtter version of me with agility
No you can't fake reality
Ogun, principality and calamity
Mo ti lọ, mo ti pa iyen ti
Bẹbẹ no de for jiji o shi wa n titi
Still get money like Fifty
Dripping like Fiji i be real G

Hmm, hmm, hmm, hmm hmm, hmm, hmm, hmm
2: 30 fẹlu oya ka turn up
Kilẹ to mọ hmm, hmm, hmm, hmm
Hmm, hmm, hmm, hmm ye, ye, ye
2: 30 fẹlu oya ka turn up
Kilẹ to mọ

Interpretation for


Add Interpretation

Add extended interpretation

If you know what the artist is talking about, can read between the lines, and know the history of the song, you can add interpretation to the lyrics. After checking by our editors, we will add it as the official interpretation of the song!

Latest added interpretations to lyrics

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z #
Interpret