Asake - Olorun lyrics

Asake

Asake [Ahmed Ololade] Lagos State, Nigeria

[Asake - Olorun lyrics]

Ololade mi asake emi kọ ọlọrun ma ni
Emi kọ o ọlọrun ma ni awa kọ oh oh
Emi kọ oọlọrun ma ni

Ta lo gbọn t'olorun (Ọmọ ọgbọn)
Kosi anybody to lo gbon t'olorun
Ti wọn ba buga ẹ oya gba fun olorun
Awọn ti wọn buga mi wọn ti sapa mọ
Wọn ti sapa mọ

Emi kọ ọlọrun ma ni (Ọlọrun ma ni)
Emi kọ o ọlọrun ma ni awa kọ oh oh
Ọlọrun ma ni (Oh oh oh) emi kọ ọlọrun ma ni

Ọmọ no be me shebi na God
Carry me from down straight to the top
2020 it was real tough
Fall for ground almost gave up
Mo fun won lo ọmọ ọpe mo de je lo
Go naked in my room and speak to God
Baba god I no sabi all


So guide me as I dey move on on on

Ta lo gbọn t'olorun
Kosi anybody to lo gbon t'olorun
Ti wọn ba buga ẹ oya gba fun olorun
Awọn ti wọn buga mi wọn ti sapa mọ
Wọn ti sapa mọ

Emi kọ ọlọrun ma ni (Ọlọrun ma ni)
Emi kọ o ọlọrun ma ni awa kọ oh oh
Ọlọrun ma ni (Oh oh oh) emi kọ ọlọrun ma ni
Emi kọ ọlọrun ma ni (Ọlọrun ma ni)
Emi kọ o ọlọrun ma ni awa kọ oh oh
Ọlọrun ma ni (Oh oh oh) emi kọ ọlọrun ma ni

Nkan kan o gbọdọ se awọn ọmọ ologo o
Mimi kan o gbọdọ mi awọn ọmọ ọlọrun o
Alhamdulillah I’m a brand new man
Tune in to the king of sounds and blues

Interpretation for


Add Interpretation

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z #
Interpret