Chidinma - Ko S'Oba Bire lyrics

[Chidinma - Ko S'Oba Bire lyrics]

Laye Lorun Kosoba Biire
(Laye Lorun Kosoba Biire)
Eleru Niyin, Alagbawi Eda’O
(Laye Lorun Kosoba Biire)
Aduro Tini, Lojo Iponju Mi O
(Laye Lorun Kosoba Biire)
Oran Ni Nise, Atu Sini Lo O
(Laye Lorun Kosoba Biire)

Gbigbe Ga,  Loruko Re tito Bi, Loruko Baba
Talaba Fi Owe, Ekun Oko Pharaoh
Hossana Iwo Lo Peye
Oforun Nikan, Se Kiki Da Wura
Ogba Mi Lowo Ota Aye Mi O
Ose O, Kosoba Biire

Laye Lorun Kosoba Biire
(Laye Lorun Kosoba Biire)
Eleru Niyin, Alagbawi Eda’O
(Laye Lorun Kosoba Biire)
Aduro Tini, Lojo Iponju Mi O


(Laye Lorun Kosoba Biire)
Oran Ni Nise, Atu Sini Lo O
(Laye Lorun Kosoba Biire)

Olugbega Mi, Atoba Tele
Oluwasanmi, Awe Maye Hun
Onibu Ola, Ola yan Turu
Atobiloba, Adi Ma Se Tu
Mojuba Fun Alada Wura
Mo Kira Fun Oba Aye Mi O ose O, Kosoba Biire

Talaba Fi Owе, Ekun Oko Pharaoh
Hossana Iwo Lo Peye
Oforun Nikan, Se Kiki Da Wura
Ogba Mi Lowo Ota Ayе Mi O
Ose O, Kosoba Biire

Laye Lorun Kosoba Biire
(Laye Lorun Kosoba Biire)
Eleru Niyin, Alagbawi Eda’O
(Laye Lorun Kosoba Biire)
Aduro Tini, Lojo Iponju Mi O
(Laye Lorun Kosoba Biire)
Oran Ni Nise, Atu Sini Lo O, Ose
(Laye Lorun Kosoba Biire)

Interpretation for


Add Interpretation

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z #
Interpret