Chidinma - Òsùbà lyrics

[Chidinma - Òsùbà lyrics]

Atógbára léé o ah ah ah ahahah
Ah ah ah ahahah ah ah ah ahahah
Ìbèrù kò sí fún mi ààyà ò fò mí o
Aládé wúrà olórun tó ga jù
Olódodo taló to ò
Taló jú o lo báàmí eni tó mo wà
Oba tó mo wá tó mo ohun gbogbo
Osuba olórun ijáíyà
Gbani gbani olórun ansáyà eni tó lemìí mi
Móò dé osuba olórun ijáíyà
Osuba olórun ijáíyà
Gbani gbani olórun ansáyà eni tó lemìí mi
Móò dé ooolódùmárè oo
Oba'kódáayé oo ògbìgbàtíngbaaraiilara
Asòròmayèohun oo ògbeninííjà
Kéruobónijà òpin òkun níí yà
Ojí okú dìde ìbàre mà rèé sir
Eléburù ìké níì ó eni tó mo wà
Oba tó mo wà tó mo ohun gbogbo
Osuba olórun ijáíyà osuba olórun ijáíyà
Gbani gbani olórun ansáyà eni tó lemìí mi


Móò dé osuba olórun ijáíyà
Gbani gbani olórun ansáyà eni tó lemìí mi
Móò dé oníbú ayé ò
Gagun gagun òde òrun o
Oba tín be níbi gbogbo àkìjúbà
Àpèjúbà àsàjúbà
Osuba re rèé osuba re rèé
Osuba re re o

Interpretation for


Add Interpretation

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z #
Interpret