Olamide, Qdot Alagbe - Ibadan lyrics

Olamide

Olamide [Olamide Gbenga Adedeji] Bariga, Lagos State, Nigeria 🇳🇬

[Olamide, Qdot Alagbe - Ibadan lyrics]

Bi sekere ba ti dun oo konga a te le
A te le ijo ma tele
Antrans ko gi le o fun mi jaree
Lateko de challengi a gba gurumaraji
Awole pelu bugati ankara lori fasasi
Idi n be n'ibadan o oke be n'ibadan o
Idi arere idi ayunre oke sango oke mo po
Ema je ko di ja olosho yapa ni bodija o
Pelu sokoto pe n pe awon omo mi ni mo lete
Ema soko fun eye twitter
Alomo meta feya speaker
Furo rabata fe ya bumber
Them say them to buggi down
Ibadan ni mo wa o ibadan ni mo re o
Ibadan ni mo wa o ibadan ni mo re o
Be wa deko be ba ni le ibadan ni mo wa oo
Ibadan ni mo wa oo
E shoutout si awon omo uni
Leed city de badan poly
Ebami ki kunle silencer
Omo musulumi to fa poli ero to lo london


Ebami ki tayo dekida tiringbeku teletele
Omo ibadan to di nigga omo woli to n fa taba
Basira su sara ko ta ba
Omugo fe high ogun lada
Won de ni momo re feya fada
Qdot fe silekun fe kun
O yo tan owa be kun bekun
I turn up tan osi seku
Ka to fi embivadale le odi seven
Ibadan ni mo wa o ibadan ni mo re o
Ibadan ni mo wa o ibadan ni mo re o
Be wa deko be ba ni le ibadan ni mo wa oo
Ibadan ni mo wa oo ni le oluyole ooo
Awon omo lagelu ujo sokky mo gbe wa o
No be skelewu atana wole pelu sanpeni
Ki ni a de temi complaini
Pe owo afefe la fi sustaini
Ahhen ti naira ba ti tan
Mabinu ma ko pounsi jade
Ko fun mi lolosho to wo gown
Won fun mi lorogbo to ti brown
Eyi ko lemaso fun wa pe oshogbo ti di town
Eeeeen we rocking gucci gucci
Ajoko sori chair kusin
Eran chikin la gbe ah nu jawee
Ibadan ni mo wa o ibadan ni mo re o
Ibadan ni mo wa o ibadan ni mo re o
Be wa deko be ba ni le ibadan ni mo wa oo
Ibadan ni mo wa oo ikorodu lo ga wa ooo
O Nana, nananana
Ni Ile oluyole Omo a fi ikarahun fo’ko mu
Nana nana sakoyo pami o sha
Ani ki mami high flyer ni badan
Eleshi money abiodun Olayinka
Gulu gulu lo London mr Ayodele po money
Olojo de olamide badoo
Ibadan ni mo wa o ibadan ni mo re o
Ibadan ni mo wa o ibadan ni mo re o
Be wa deko be ba ni le ibadan ni mo wa oo

Interpretation for


Add Interpretation

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z #
Interpret